Jẹ́nẹ́sísì 31:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lábánì sì lọ sínú àgọ́ Jákọ́bù àti ti Líà àti ti àwọn ìránṣẹ́-bìnrin méjèèjì, kò sì rí ohunkóhun. Lẹ́yìn ìgbà tí ó jáde nínú àgọ́ Líà ni ó lọ sí àgọ́ Rákélì.

Jẹ́nẹ́sísì 31

Jẹ́nẹ́sísì 31:23-39