Jẹ́nẹ́sísì 31:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nísin yìí, ìwọ ti lọ nítorí ìwọ fẹ́ lati padà lọ sí ilé baba rẹ, ṣùgbọ́n èéṣe tí ìwọ fi jí àwọn òrìṣà mi?”

Jẹ́nẹ́sísì 31

Jẹ́nẹ́sísì 31:22-35