Jẹ́nẹ́sísì 31:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo ní agbára láti ṣe ọ ni ibi, ṣùgbọ́n ní òru àná, Ọlọ́run baba rẹ sọ fún mi pé, kí èmi ṣọ́ra, kí èmi má ṣe sọ ohun kan fún ọ, ìbáà ṣe rere tàbí búburú.

Jẹ́nẹ́sísì 31

Jẹ́nẹ́sísì 31:19-32