Jẹ́nẹ́sísì 31:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Dájúdájú gbogbo ọrọ̀ ti Ọlọ́run gbà lọ́wọ́ baba wa fún ọ, tiwa àti ti àwọn ọmọ wa ní í ṣe. Nítorí náà ohun gbogbo tí Ọlọ́run bá páṣẹ fun ọ láti ṣe ni kí ìwọ kí ó ṣe.”

Jẹ́nẹ́sísì 31

Jẹ́nẹ́sísì 31:14-20