Jẹ́nẹ́sísì 31:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àjèjì ha kọ́ ni ó kà wá sí? Kì í ṣe pé torí pé ó tà wá nìkan, ṣùgbọ́n ó ti ná gbogbo owó tí ó gbà lórí wa tán.

Jẹ́nẹ́sísì 31

Jẹ́nẹ́sísì 31:7-24