Jẹ́nẹ́sísì 30:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Inú sì bí Jákọ́bù sí i, ó sì wí pé, “Èmi ha wà ní ipò Olúwa, ẹni tí ó mú ọ yàgàn bí?”

Jẹ́nẹ́sísì 30

Jẹ́nẹ́sísì 30:1-10