Jẹ́nẹ́sísì 3:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó dáhùn pé, “Mo gbúrò ó rẹ̀ nínú ọgbà, ẹ̀rù sì bà mí nítorí pé, mo wà ní ìhòòhò, mo sì fi ara pamọ́.”

Jẹ́nẹ́sísì 3

Jẹ́nẹ́sísì 3:2-14