Jẹ́nẹ́sísì 29:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí wọ́n sì ti ń sọ̀rọ̀ lọ́wọ́ ni Rákélì dé pẹ̀lú agbo àgùntàn baba rẹ̀, nítorí darandaran ni òun náà.

Jẹ́nẹ́sísì 29

Jẹ́nẹ́sísì 29:8-18