Jẹ́nẹ́sísì 29:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n dá a lóhùn pé, “Àwa kì í yí òkúta kúrò ní ẹnu kànga láti pọn omi fún àwọn ẹran títí gbogbo àwọn darandaran àti àwọn ẹran yóò fi péjọ tán.”

Jẹ́nẹ́sísì 29

Jẹ́nẹ́sísì 29:6-9