Jẹ́nẹ́sísì 29:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n nígbà tí ó di òru, Lábánì mú Líà tọ Jákọ́bù lọ. Jákọ́bù sì bá a lòpọ̀.

Jẹ́nẹ́sísì 29

Jẹ́nẹ́sísì 29:20-33