Jẹ́nẹ́sísì 29:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lábánì sì pe gbogbo ènìyàn ibẹ̀ jọ, ó sì ṣe àṣè ìyàwó fún wọ́n.

Jẹ́nẹ́sísì 29

Jẹ́nẹ́sísì 29:20-28