Jẹ́nẹ́sísì 29:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lábánì sì dáhùn wí pé, “Ó kúkú sàn kí ń fi fún ọ, ju kí ń fi fún ẹlòmíràn lọ, nítorí wà ní ọ̀dọ̀ mi.”

Jẹ́nẹ́sísì 29

Jẹ́nẹ́sísì 29:17-22