Jẹ́nẹ́sísì 29:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jákọ́bù sì fẹ́ràn Rákélì, ó sì wí fún baba rẹ̀ pé, “Èmi yóò ṣiṣẹ́ sìn ọ fún ọdún méje, bí ìwọ yóò bá fún mi ní Rákélì ọmọ rẹ ní aya.”

Jẹ́nẹ́sísì 29

Jẹ́nẹ́sísì 29:14-23