Jẹ́nẹ́sísì 28:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì pe orúkọ ibẹ̀ ní Bẹ́tẹ́lì (Ilé Ọlọ́run) bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ìlú náà ń jẹ́ Lúsì tẹ́lẹ̀ rí.

Jẹ́nẹ́sísì 28

Jẹ́nẹ́sísì 28:11-22