Jẹ́nẹ́sísì 28:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jákọ́bù sì dìde ní kùtùkùtù òwúrọ̀, ó sì gbé òkúta tí ó fi ṣe ìrọ̀rí lélẹ̀ bí òpó, ó sì da òróró si lórí.

Jẹ́nẹ́sísì 28

Jẹ́nẹ́sísì 28:13-20