Jẹ́nẹ́sísì 28:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi wà pẹ̀lú rẹ, èmi yóò sì pa ọ mọ́ ní ibikíbi tí ìwọ bá lọ, èmi yóò sì mú ọ padà wá sí ilẹ̀ yìí ní àlàáfíà. Èmi kì yóò fi ọ sílẹ̀ ní ìgbà kan, títí tí èmi yóò fi mú gbogbo ìlérí mi ṣẹ.”

Jẹ́nẹ́sísì 28

Jẹ́nẹ́sísì 28:12-21