Jẹ́nẹ́sísì 28:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìran rẹ yóò pọ̀ bí erùpẹ̀ ilẹ̀, ìwọ yóò sì tànkálẹ̀ dé ìlà oòrùn àti ìwọ̀ oòrùn, àti dé gúsù àti àríwá. A ó sì bùkún gbogbo orílẹ̀ èdè ayé nípaṣẹ̀ ìwọ àti àwọn ọmọ rẹ.

Jẹ́nẹ́sísì 28

Jẹ́nẹ́sísì 28:8-19