Jẹ́nẹ́sísì 27:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni ó gbé ẹran dídùn náà àti oúnjẹ tí ó ti sè lé Jákọ́bù ọmọ rẹ̀ lọ́wọ́.

Jẹ́nẹ́sísì 27

Jẹ́nẹ́sísì 27:14-18