Jẹ́nẹ́sísì 26:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ísáákì sì kọ́ pẹpẹ kan ṣíbẹ̀, ó sì pe orúkọ Olúwa. Níbẹ̀ ni ó pàgọ́ rẹ̀ sí, àwọn ìránṣẹ́ rẹ sì gbẹ́ kànga kan ṣíbẹ̀.

Jẹ́nẹ́sísì 26

Jẹ́nẹ́sísì 26:18-26