Jẹ́nẹ́sísì 24:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìránṣẹ́ náà sì fi ọwọ́ rẹ̀ sí abẹ́ itan Ábúráhámù olúwa rẹ̀, ó sì búra fún nítorí ọ̀rọ̀ náà.

Jẹ́nẹ́sísì 24

Jẹ́nẹ́sísì 24:7-19