Jẹ́nẹ́sísì 24:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìránṣẹ́ náà sì mú ràkunmí mẹ́wàá, pẹ̀lú onírúurú ohun dáradára láti ọ̀dọ̀ olúwa rẹ̀, ó sì dìde ó sì lọ sí Aramu-Náháráímù, sí ìlú Náhórì,

Jẹ́nẹ́sísì 24

Jẹ́nẹ́sísì 24:7-16