Jẹ́nẹ́sísì 24:63 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ísáákì sáà jáde lọ sí oko ni ìrọ̀lẹ́ láti ṣe àsàrò, bí ó sì ti gbé ojú sókè, ó rí àwọn ràkunmí tí ń bọ̀ wá.

Jẹ́nẹ́sísì 24

Jẹ́nẹ́sísì 24:57-67