Jẹ́nẹ́sísì 24:62 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ísáákì sì ń ti Bia-Lahai-Róì bọ, nítorí ìhà gúsù ni ó ń gbé.

Jẹ́nẹ́sísì 24

Jẹ́nẹ́sísì 24:52-67