Jẹ́nẹ́sísì 24:55 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n arákùnrin Rèbékà àti ìyá rẹ̀ fèsì pé, “A fẹ́ kí Rèbékà wà pẹ̀lú wa fún nǹkan bí ọjọ́ mẹ́wàá sí i, lẹ́yìn ìyẹn, ìwọ le máa mu lọ.”

Jẹ́nẹ́sísì 24

Jẹ́nẹ́sísì 24:54-59