Jẹ́nẹ́sísì 24:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kíyèsí i, mo dúró lẹ́gbẹ̀ẹ́ yìí, àwọn ọmọbìnrin ìlú yìí sì ń jáde wá pọn omi.

Jẹ́nẹ́sísì 24

Jẹ́nẹ́sísì 24:7-21