Jẹ́nẹ́sísì 24:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì gbàdúrà wí pé, “Olúwa, Ọlọ́run Ábúráhámù olúwa à mi; jẹ́ kí n ṣe àṣeyọrí lónìí, sì fi àánú hàn fún Ábúráhámù olúwa mi.

Jẹ́nẹ́sísì 24

Jẹ́nẹ́sísì 24:6-16