Jẹ́nẹ́sísì 23:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ábúráhámù sì gba ohun tí Éfúróni wí, ó sì wọn iye owó fàdákà náà lójú gbogbo ènìyàn: irínwó owó idẹ fàdákà gẹ́gẹ́ bí ìwọ̀n oníṣòwò ayé ìgbà náà.

Jẹ́nẹ́sísì 23

Jẹ́nẹ́sísì 23:6-19