Jẹ́nẹ́sísì 23:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Gbọ́ tèmi Olúwa mi, irínwó (400) òsùwọ̀n owó fàdákà ni ilẹ̀ náà, ṣùgbọ́n kín ni ìyẹn já mọ láàrin àwa méjèèjì? Ṣáà sin òkú ù rẹ.”

Jẹ́nẹ́sísì 23

Jẹ́nẹ́sísì 23:5-20