Jẹ́nẹ́sísì 23:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ṣárà sì pé ọmọ ọdún mẹ́tà-dín-láàádóje (127)

2. ó sì kú ní Kíríátì-Áríbà (ìyẹn ní Hébúrónì) ní ilẹ̀ Kénánì, Ábúráhámù lọ láti sọ̀fọ̀ àti láti sunkún nítorí Ṣárà.

Jẹ́nẹ́sísì 23