Jẹ́nẹ́sísì 22:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àlè rẹ̀ tí ń jẹ́ Réhúmà náà bí àwọn ọmọkùnrin wọ̀nyí fun un: Tébà, Gáhámù, Táhásì àti Máákà.

Jẹ́nẹ́sísì 22

Jẹ́nẹ́sísì 22:19-24