Jẹ́nẹ́sísì 22:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ábúráhámù sì gbé igi ẹbọ ṣíṣun náà ru Ísáákì, òun fúnra rẹ̀ sì mú iná àti ọ̀bẹ. Bí àwọn méjèèjì ti ń lọ,

Jẹ́nẹ́sísì 22

Jẹ́nẹ́sísì 22:1-10