Jẹ́nẹ́sísì 22:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ańgẹ́lì Olúwa sì tún pe Ábúráhámù láti ọ̀run lẹ́ẹ̀kejì.

Jẹ́nẹ́sísì 22

Jẹ́nẹ́sísì 22:9-21