Jẹ́nẹ́sísì 21:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì fi kún un pé, “Ta ni ó le sọ fún Ábúráhámù pé, Ṣárà yóò di ọlọ́mọ? Ṣíbẹ̀ṣíbẹ̀, mo sì tún bí ọmọ fún Ábúráhámù ní ìgbà ogbó rẹ.”

Jẹ́nẹ́sísì 21

Jẹ́nẹ́sísì 21:1-14