Jẹ́nẹ́sísì 21:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣárà sì wí pé, “Ọlọ́run ti pa mí lẹ́rìn-ín. Gbogbo ẹni tí ó bá sì gbọ́ pé mo bímọ yóò rẹ́rìn-ín pẹ̀lú mi.”

Jẹ́nẹ́sísì 21

Jẹ́nẹ́sísì 21:1-13