Jẹ́nẹ́sísì 21:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó da lóhùn pé “Gba àwọn abo ọ̀dọ́-àgùtàn méje wọ̀nyí lọ́wọ́ mi gẹ́gẹ́ bí ẹ̀rí pé èmi ni mo gbẹ́ kànga yìí.”

Jẹ́nẹ́sísì 21

Jẹ́nẹ́sísì 21:25-33