Jẹ́nẹ́sísì 21:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ábímélékì sì béèrè lọ́wọ́ Ábúráhámù pé, “Kín ni ìtumọ̀ yíyà tí ìwọ ya àwọn ọ̀dọ́ àgùntàn méje wọ̀nyí sọ́tọ̀ sí.”

Jẹ́nẹ́sísì 21

Jẹ́nẹ́sísì 21:26-34