Jẹ́nẹ́sísì 21:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ábúráhámù sì sọ orúkọ ọmọ náà tí Sárà bí fun un ní Ísáákì.

Jẹ́nẹ́sísì 21

Jẹ́nẹ́sísì 21:1-13