Jẹ́nẹ́sísì 21:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣárà sì lóyún, ó sì bí ọmọkùnrin kan fún Ábúráhámù ní ọjọ́ ogbó rẹ̀, ní àkókò náà gan-an tí Ọlọ́run ti ṣèlérí fún un.

Jẹ́nẹ́sísì 21

Jẹ́nẹ́sísì 21:1-3