Jẹ́nẹ́sísì 21:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọ̀rọ̀ náà sì ba Ábúráhámù lọ́kàn jẹ́ gidigidi nítorí ọmọ rẹ̀ náà sáà ni Isìmàẹ́lì i ṣe.

Jẹ́nẹ́sísì 21

Jẹ́nẹ́sísì 21:1-17