Jẹ́nẹ́sísì 21:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

ó sì wí fún Ábúráhámù pé, “Lé ẹrúbìnrin yìí àti ọmọ rẹ̀ jáde, nítorí ọmọ ẹrú yìí kò ní bá ọmọ mi Ísáákì pín ogún.”

Jẹ́nẹ́sísì 21

Jẹ́nẹ́sísì 21:1-16