Jẹ́nẹ́sísì 2:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Orúkọ èkínní ni Písónì: òun ni ó sàn yí gbogbo ilẹ̀ Háfílà ká, níbi tí wúrà gbé wà.

Jẹ́nẹ́sísì 2

Jẹ́nẹ́sísì 2:1-21