Jẹ́nẹ́sísì 2:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Odò kan sì ń ti Édẹ́nì sàn wá láti bu omi rin ọgbà náà, láti ibẹ̀ ni odò náà gbé ya sí ipa mẹ́rin.

Jẹ́nẹ́sísì 2

Jẹ́nẹ́sísì 2:1-18