Jẹ́nẹ́sísì 19:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lọ́tì sì jáde láti pàdé wọn, ó sì ti ilẹ̀kùn lẹ́yìn rẹ̀ bí ó ti jáde.

Jẹ́nẹ́sísì 19

Jẹ́nẹ́sísì 19:1-11