Jẹ́nẹ́sísì 19:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n pe Lọ́tì pé, “Àwọn ọkùnrin tí ó wọ̀ sí ilé rẹ lálẹ́ yìí ńkọ́? Mú wọn jáde fún wa, kí a le ní ìbálòpọ̀ pẹ̀lú wọn.”

Jẹ́nẹ́sísì 19

Jẹ́nẹ́sísì 19:3-14