Jẹ́nẹ́sísì 19:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní òru ọjọ́ náà, wọ́n rọ baba wọn ní ọtí yó. Èyí ẹ̀gbọ́n sì wọlé tọ̀ ọ́, ó sì bá a lò pọ̀, baba wọn kò mọ̀ ìgbà tí ó sùn ti òun àti ìgbà tí ó dìdè.

Jẹ́nẹ́sísì 19

Jẹ́nẹ́sísì 19:24-38