Jẹ́nẹ́sísì 19:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wá, jẹ́ kí a mú bàbá wa mu ọtí yó, kí ó ba à le bá wa lò pọ̀, kí àwa kí ó lè bí ọmọ, kí ìran wa má ba à parẹ́.”

Jẹ́nẹ́sísì 19

Jẹ́nẹ́sísì 19:29-37