Jẹ́nẹ́sísì 19:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tètè! Sá lọ ṣíbẹ̀, nítorí èmi kò le ṣe ohun kan àyàfi tí ó bá dé ibẹ̀,” (ìdí nìyí tí a fi ń pe ìlú náà ní Ṣóárì).

Jẹ́nẹ́sísì 19

Jẹ́nẹ́sísì 19:21-23