Jẹ́nẹ́sísì 19:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì wí fún un pé, “Ó dára, mo gba ẹ̀bẹ̀ rẹ. Èmi kì yóò run ìlú náà tí ìwọ sọ̀rọ̀ rẹ̀.

Jẹ́nẹ́sísì 19

Jẹ́nẹ́sísì 19:16-29