Jẹ́nẹ́sísì 17:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n èmi yóò fi ìdí májẹ̀mú mi múlẹ̀ pẹ̀lú Ísáákì, ẹni tí Ṣárà yóò bí fún ọ ni ìwòyí àmọ́dún.”

Jẹ́nẹ́sísì 17

Jẹ́nẹ́sísì 17:11-27