Jẹ́nẹ́sísì 17:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ábúráhámù sì wí fún Ọlọ́run pé, “Ṣá à jẹ́ kí Ísímáélì kí ó wà láàyè lábẹ́ ìbùkún rẹ.”

Jẹ́nẹ́sísì 17

Jẹ́nẹ́sísì 17:17-19